Romans 11:11

Ìran aláìkọlà pín nínú ìgbàlà àwọn ọmọ Israẹli

11 aǸjẹ́ mo ní, wọ́n ha kọsẹ̀ kí wọn kí ó lè ṣubú? Kí a má ri i, ṣùgbọ́n nípa ìṣubú wọn, ìgbàlà dé ọ̀dọ̀ àwọn Kèfèrí, láti mú Israẹli jowú.
Copyright information for YorBMYO